Wo ẹ̀sà nínú àwọn àwòran Áfríka tó rẹwà jù l'ọṣẹ̀ yìí.

Ẹ̀ṣà nínú àwọn àwòran to rẹwà jù l'Áfríkà àti tí àwọn èèyán Áfríkàl'ọ́ṣẹ̀ yìí.

Okúnrín kan dùbúlẹ̀ pẹ̀lu àgbẹ́lébu nígbá nígbá ere órí ìtàge kikán Jésù mọ àgbelébu l'ọjọ́ Jímò rere nígboro Èkó l'ọgbọ̀jọ́ osù kẹ́tá, 2018. Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Árákùnrín kán dùbúlẹ̀ nígbá ere órí ìtàge kikán Jésù mọ àgbelébu l'ọjọ́ Jímò rere nígboro Èkó
Wọn ń rẹ ọmọbìnrín kan nigba tó ń sunkún nitórí ere órí ìtàge l'ogunjọ oṣù kẹtá, ọdún 2018 Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Wọn ń pẹ̀tù s'ọmọbìnrín kan nínú nigbà tó ń sunkún nitórí ere órí ìtàge náà...
Nigba náà ni ọmọkùnrin yìí ń gbádúrà ní olú ìlú Kenya, Nairobi., l'ọjọ kin ní oṣù kẹrín , ọdún 2018. Image copyright Reuters
Àkọlé àwòrán Nigba náà ni ọmọkùnrin yìí ń gbádúrà ní olú ìlú Kenya, Nairobi.
Harun Karanja, tó ni ìsò ohún ọ̀wọn lori Facebook , ń lo ẹ̀rọ ìbanisọ̀rọ̀ rẹ̀ lati fi wọ opo Facebook rẹ̀ ni agbẹ̀gbẹ̀ Rift Valley lórílẹ̀ede Kenya lójọ́ kejìdínlọgbọ̀n oṣu kẹ̀ta, ọdún 2018. Image copyright Reuters
Àkọlé àwòrán Harun Karanja, tó ni ìsò ohún ọ̀wọn lori Facebook , ń lo ẹ̀rọ ìbanisọ̀rọ̀ rẹ̀ lati fi wọ opo Facebook rẹ̀ ni agbẹ̀gbẹ̀ Rift Valley lórílẹ̀ede Kenya.
Okùnín kan to n ṣiṣẹ́ nibi ti wọn ti ń kòle kan ni ìlu Goma, olu ìlu kan ni ìlà-óòrun Democratic Republic of Congo... Image copyright Reuters
Àkọlé àwòrán Okùnín kan to n ṣiṣẹ́ nibi ti wọn ti ń kòle kan ni ìlu Goma, olu ìlu kan ni ìlà-óòrun Democratic Republic of Congo...
Nígbà tí àwọn ìyókù rẹ̀ ń ṣiṣẹ́ lorí àga pákó Image copyright Reuters
Àkọlé àwòrán Nígbà tí àwọn ìyókù rẹ̀ ń ṣiṣẹ́ lorí àga pákó
Ni ìgboro Durban tó wà letí omí ní orílẹ̀ede South Africa l'ọjọ́ Ajé (Monday), wọ́n ṣe àfihán àworán olóògbẹ Winnie Madikizela-Mandela tó jẹ gbajúgbajàá èèyàn to gb'ógún ti ìjọbá ẹlẹ́yàmẹ́yà apatheid tú kú lẹní ọdún mọkàndinlọ́gọ́rín (81) Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Ni ìgboro Durban tó wà letí omí ní orílẹ̀ede South Africa l'ọjọ́ Ajé (Monday), wọ́n ṣe àfihán àworán olóògbẹ Winnie Madikizela-Mandela tó jẹ gbajúgbajàá èèyàn to gb'ógún ti ìjọbá ẹlẹ́yàmẹ́yà apatheid tú kú lẹní ọdún mọkàndinlọ́gọ́rín (81)
Nigbà ti àwọn obìnrin yìí ń korín yin Madikizela-Mandela nilú Soweto Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Nigbà ti àwọn obìnrin yìí ń korín yin Madikizela-Mandela nilú Soweto
Ni olú ìluTunisia, Tunis, ol'gun ka ń lùlù nibi ajọ́ ìlọsíwajú ni ìlànà Islam Image copyright Reuters
Àkọlé àwòrán Ni olú ìluTunisia, Tunis, ol'gun ka ń lùlù nibi ajọ́ ìlọsíwajú ni ìlànà Islam
Ni orílẹ̀edé Australia Salome Nyirarukundo ti ìlẹ Rwanda gbé àsìá orílẹ̀edé rẹ̀ l'ọwọ nigbá ayẹ́yẹ́ sisí ìdijẹ ere ìdaraya Commonwealth Games. Image copyright Reuters
Àkọlé àwòrán Ni orílẹ̀edé Australia Salome Nyirarukundo ti ìlẹ Rwanda gbé àsìá orílẹ̀edé rẹ̀ l'ọwọ nigbá ayẹ́yẹ́ sisí ìdijẹ ere ìdaraya Commonwealth Games.
L'ọjọ́ Ẹ́tì awọṣọ kan ń ṣe àfihan aṣọ kan ni Accra Image copyright EPA
Àkọlé àwòrán L'ọjọ́ Ẹ́tì awọṣọ kan ń ṣe àfihan aṣọ kan ni Accra
L'ọjọ Àbamẹtá (Saturday), obìnrín kan ń dibò nigba ìsòri kejí ìbò ààrẹ orilẹedé Sierra Leone... Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán L'ọjọ Àbamẹtá (Saturday), obìnrín kan ń dibò nigba ìsòri kejí ìbò ààrẹ orilẹedé Sierra Leone...
Ìkedé Ọjọ́rú wipe ọmọ ẹgbẹ́ alátákò, Julius Maada Bio, lo jẹ ki àwọn ọlatilẹyin rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ si dun nu ni olu ìlú orílẹ̀ede náà, Freetown. Image copyright AFP
Àkọlé àwòrán Ìkedé Ọjọ́rú wipe ọmọ ẹgbẹ́ alátákò, Julius Maada Bio, lo jẹ ki àwọn ọlatilẹyin rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ si dun nu ni olu ìlú orílẹ̀ede náà, Freetown.

Orisun àwòran: AFP, Reuters, EPA àti Getty Images.

Ní àyíká BBC