Ọlọ́pàá Kwara: À ń wá àwọn adigunjalè tó pa èèyàn méjìlá

Àwọn adigunjalè náà pa ọlọ́pàá mẹ́fà àti àwọn ará ìlú mẹ́fà níbi ìkọlù sí àwọn ilé ìfowópamọ́ márùń ní ìlú Ọ̀ffà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: