Saraki bẹ Ọlọ́ffá atí Ọ́ffà wò lori ìkọ̀lú ọlọ́ṣà

Bukola Saraki

Oríṣun àwòrán, Twitter/@bukolasaraki

Ààrẹ ilé ìgbìmọ ásòfin àgbà, Bukọ́lá Sàràkí, bẹ ilu Ọ̀ffà wo lori ìkọ́lú àwọn ọlọ́ṣa l'ọjọ́ Àbámẹ́tá (Saturday).

Sàràki ba Ọlọ́ffá ìlú Ọ́ffà, Ọ́bá Muftau Gbàdámasí, ati àwọn ará ìlú kẹdùn loí òfo ẹ̀mi àti dúkìà tí wọn ṣe nipá ìkọlú àwọn ọlọṣa ti wọn ya wọ ìlú náà.

Oríṣun àwòrán, Twitter/@bukolasaraki

L'Ọjọ́bọ ni àwọn adigunjalè ya wọ ìlú Ọ̀ffà ti wọn si wọn si jalè ni ilé ìfowópamọ́ marún.