Buhari: Mo fẹ́ se sáà kejì lórí oyè

Ààrẹ Muhammadu Buhari Image copyright Reuters
Àkọlé àwòrán Àwọn ọmọ Nàíjíríà ti ń fojú sọ́nà láti mọ bóyá Buhari yóò se sáà kejì

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti kéde pe òun fẹ́ ṣe ìjọba ni sáà kéjì.

Bashir Ahmad, tíí se òlùrànlọ́wọ́ fún ààrẹ lórí ẹ̀rọ áyélujará, ló fi ọ̀rọ̀ náà sọwọ si orí opó Twitter rẹ̀.

Lẹyín rẹ̀ ni gómìnà ìpinlẹ Kaduna, Nasir El'Rufai náà kéde ìròyìn náà lórí Facebook rẹ̀

A yóò máa mú èrò àwọn aaráàlú wá fún yín lórí ìgbésẹ̀ yìí tó bá yá.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: