OPC sàlàyé nípa wàhálà Ìjẹ̀bú Igbó
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Wàhálà Ìjẹ̀bú Igbó: OPC sọ ohun tó bí ìsẹ̀lẹ̀ náà

Ẹgbẹ́ ọmọ bíbí Oòduà OPC sàlàyé nípa ohun tó bí ìsẹ̀lẹ̀ ìpànìyàn tó wáyé ní Ìjẹ̀bú Igbó.

Gẹ́gẹ́ bíí alukoro fún ẹgbẹ́ OPC, Sina Akinpẹlu ti sàlàyé, OPC kò ní fa wàhálà kankan lẹ́sẹ̀ mọ́.