Ọwọ́ tẹ afurasí 29 lórí ìpànìyàn Ìjẹ̀bú Igbó
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ìpànìyàn Ìjẹ̀bú Igbó: Ọwọ́ Ọlọ́pàá tẹ afurasí 29

Alukoro fún Iléesẹ́ Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ògùn, Abimbọla Oyeyẹmi ni, ọwọ́ Ọlọ́pàá ti tẹ afurasí mọ́kàndínlọ́gbọ̀n nítorí ìpànìyàn tó wáyé ní Ìjẹ̀bú Igbó.