Masazo Nonaka láti ilẹ̀ Japan ni ẹni tuntun tó dàgbà jù lọ lágbàyé

Masazo Nonaka láti ilẹ̀ Japan ni ẹni tuntun tó dàgbà jù lọ lágbàyé

Ọmọ ilẹ Japan, Masazo Nonaka ni ẹni to dagbaju lagbaye

Ati ri ẹni tuntun to dagba ju lọ lagbaye, lẹni ọdun 112

Masazo Nonaka lati Ashoro ni Japan ni wọn bi lọdun 1905

O fẹran lati ma lọ si ibi isaraloge ati ki o ma jẹ akara oyinbo ẹlẹrindodo

Orilẹede Japan ni awon arugbo to to 68,000 ti ọjọ ori wọn ju ọgorun lọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: