Kókó ìròyìn t'òní: Ènìyàn 200m ló wà ní Nàíjíríà, Ìsìnkú Winnie Mandela

Eyi ni awọn akojọpọ iroyin ti toni.

Ìkànìyàn: A ti tó igba mílíọ́nù èèyàn ní Nàìjíríá

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ó ti di igba mílíọ̀nù ènìyàn ó dín díẹ̀ tó wà lórílẹ́èdè Nàìjíríá

Lọ́wọ́lọ́wọ́, òǹkà iye ènìyàn tó wà lórílẹ́èdè Nàìjíríá ti sún mọ́ mílíọ̀nù lọ́nà igba.

Èyí ni àtẹ̀jáde tó wá láti ọ̀dọ̀ àjọ tó ńrísí ìkànìyàn lórílẹ́èdè Nàìjíríá eléyìí tó fi orílẹ̀èdè yìí sí ipò keje nínú àwọn orílẹ̀èdè tó pọ̀ jù lágbayé.

Ní Àwòrán: Ètò Ìsìnkú Winnie Madikizela-Mandela

Image copyright REUTERS
Àkọlé àwòrán Ọpọlọpọ awọn eniyan ni wọn ti wọ awọ ẹgbẹ oṣẹlu African National Congress, eyiti o fa ija si apartheid.

Ẹgbẹẹgbẹrun eniyan peju-pesẹ si ibi akanṣe eto iranti ati ayẹyẹ isnku fun gbajugbaja ọmọ orilẹede South Africa, Winnie Madikizela-Mandela. O figbakan jẹ iyawo aarẹ orilẹede South Africa tẹlẹri, Nelson Mandela ti o ku ni ọjọ keji oṣu kẹrin ọdun 2018 . Eka ẹ̀kúnréré ní bíí

Awọn nkan miran ti ẹ ni lati mọ loni

Gbọ iroyin iṣẹju kan BBC

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionÌsẹ̀lẹ̀ jákèjádò orílẹ̀èdè àgbáyé láàárín ìṣẹ́jú kan

Awọn Fidio wa fun toni:

Olú Fálaè: Orúkọ àwọn jẹgúdújẹrá tí APC tẹ̀ jáde kò tíì pé

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionOlú Fálaè: Orúkọ àwọn jẹgúdújẹrá tí APC tẹ̀ jáde kò tíì pé

Ìsẹ̀lẹ̀ Algeria: Ó tó igba ẹ̀mí tó bá bàálù tó já lọ

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionMore than 250 people have been killed after a military plane crashed in Algeria, local media report.