Ìṣẹ̀lẹ̀ Èkó: Aáwọ̀ Ọbàkan sọ ilé di áláwọ̀ méjì

Ìṣẹ̀lẹ̀ Èkó: Aáwọ̀ Ọbàkan sọ ilé di áláwọ̀ méjì

Ilé alájà méjì kan wà ládúgbò Bámgbóṣé, lágbègbè Lagos Island nílùú Èkó, tó jẹ́ abala méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.

Àwọn ọmọ bàbá méjì, tí wọn jẹ́ ọkùnrin àti obìnrin, ló jogún ilé náà.

Ó fojú hàn gbangba pé, ààrin àwọn ọmọ tó jogún ilé náà kò gún.

Abala tí wọn sì túnṣe yìí jẹ́ ti obìnrin nígbàtí abala tí kò rí àtúnṣe náà jẹ́ ti ọkùnrin.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: