Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Adekunle Ajasin, Akungba-Akoko fẹ̀hónú hàn
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Adekunle Ajasin, Akungba-Akoko fẹ̀hónú hàn ní ìpínlẹ̀ Èkó

Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Adekunle Ajasin, Akungba-Akoko tú síta kẹ̀tí-kẹ̀tí lónì''i láti fẹ̀hónú hàn lórí i àfikún owó iléèwé tí ìjọba ìpínlẹ̀ Òndò paláṣẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: