Brọ̀dá Shaggi: Shagidon ni mo gé kúrú sí Shaggi bíi ìnagijẹ nínú eré

Brọ̀dá Shaggi: Shagidon ni mo gé kúrú sí Shaggi bíi ìnagijẹ nínú eré

Gbajugbaja apanilẹrin loju opo ikansiraẹni Instagram, to tun jẹ osere tiata, Samuel Animasahun Perry salaye pe, ẹnu awọn agbero ni gareji ọkọ ero ni ero lilo inagijẹ ninu ere ti kọkọ gba ọkan oun.

Samuel fikun pe inagijẹ Shagidon lo wu oun lati jẹ, ti oun si ge kuru si Brọda Shaggi.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

O ni olukọ ati osere ni baba oun, inu ẹjẹ oun si ni isẹ apanilẹrin wa, eyi ti oun ti bẹrẹ lati kekere.

Brọda Shaggi oun n fi isẹ apanilẹrin lori Instagram bọ ẹbi ati ara, to si tun rọ awọn ọmọ Kaarọ OOjire lati maa tẹti gbọ BBC Yoruba.