Kókó ìròyìn t'òní: Wàhálà ìdàmẹ́wàá, Fáyòṣe tako Ààrẹ Bùhárí

Eyi ni awọn akojọpọ iroyin ti toni.

Kí la tún gbọ́ nípa ìdámẹ́wàá?

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán,

Kí la tún gbọ́ nípa ìdámẹ́wàá?

Laipẹ́ yii, olusọ̀aguntan ijọ RCCG, Pasito Adeboye sọ ni gbangba fun awọn ọmọ ijọ rẹ̀ wipe, ẹni ti ko ba san idamẹwa ko ni lọ si ọ̀run.

Ẹ o ranti wipe, ọrọ ti nja rain rain tẹ́lẹ̀ lori pe Daddy Freeze fesi si ọ̀rọ̀ pasitọ̀ Adeboye lori sisan idamẹ́wa leyii ti Freeze fesi pe idamẹ́wo ko pọn dandan.

Fáyóṣé fèsì lórí bí Buhari se ńdá Gaddafi lẹ́bi wàhálà darandaran

Oríṣun àwòrán, Nigeria presidency

Àkọlé àwòrán,

Fayoṣe ni awọn darandaran ti ko pa awọn ọmọ ilẹ̀ Libya ni wọn ń wá pa àwọn èèyàn ní Nàìjíríà.

Gómìnà Ayọ̀délé Fáyóṣe ti ìpínlẹ̀ Èkìtì ti sọ pé ìdójútì ńláǹlà ni Ààrẹ Mùhámádù Bùhárí ń fún orílẹ̀èdè Nàìjíríà pẹ̀lú bí ó ṣe lọ ń di ẹ̀bi gulegule àwọn darandaran lórílẹ̀èdè Nàìjíríà ru Ààrẹ Gaddafi ti ilẹ̀

Libya tó ti di olóògbé . E ka ekunrere re ni bii

Awọn nkan miran ti ẹ ni lati mọ loni

Gbọ iroyin iṣẹju kan BBC

Awọn Fidio wa fun toni

Brọdá Shaggi: Kékeré ni mo ti mọ̀ pé iṣẹ́ apanilẹ́ẹ̀rín l'ọ̀nà mi

Àkọlé fídíò,

'Kékeré ni mo ti mọ̀ pé iṣẹ́ apanilẹ́ẹ̀rín l'ọ̀nà mi'

Ẹ wo àwọn ọmọ tí bàbá wọn fi s'ílẹ̀ sálọ ní Ghana

Àkọlé fídíò,

Ẹwo awọn ọmọ ti baba wọn fi silẹ sa lọ