Akinjide Isola: Ara fu mí ní ọdún márùń sẹ́yìn pé bàbá fẹ́ pa’pòdà

Àkọ́bí olóògbé, Akinjide Isola sọ fún BBC Yorùbá wípé ara fu òun ní ọdún márùń sẹ́yìn pé bàbá Akínwùnmí Iṣọ̀lá fẹ́ pa’pòdà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè nífẹ̀ síí: