Dòdò Ìkirè: Ó dúdú lára sùgbọ́n oyin ni lẹ́nu

Dòdò Ìkirè: Ó dúdú lára sùgbọ́n oyin ni lẹ́nu

Dòdò Ìkirè jẹ́ ohun ìpanu pàtàkì nílẹ̀ Yorùba. Ìlú Ìkirè sì ni wọ́n ti máa ń se Dòdò Ìkirè.

A gbọ́ pé ọ̀gẹ̀dẹ̀ Fìkì, táa mọ̀ sí ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹ́wẹ́ tàbí páráǹtà tó pọ́n, ni wọ́n fi máa se Dòdò Ìkirè.

A leè fi Dòdò Ìkirè mu gaarìí, jẹ tàbí mu ẹ̀kọ́.

Dòdò Ìkirè dúdú lójú sùgbọ́n oyin ni lẹ́nu.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: