Ibùdó ìdalẹ̀sí Olúsosùn: Iná èèsì tún jo lẹ́ẹ̀kejì

Ibùdó ìdalẹ̀sí Olúsosùn: Iná èèsì tún jo lẹ́ẹ̀kejì

Iná èèsì tún ti jo ibùdó ìdalẹ̀sí Olúsosùn, tó wà ní agbègbè Ọjọ́ta ní ìpínlẹ̀ Èkó lẹ́ẹ̀kejì ní ọ̀sán ọjọ́ ìsẹ́gun.

Ìròyìn tó ń tẹ̀ wá lọ́wọ́ ní ń se ni gbogbo agbègbè náà kún fún èéfín, tí ọwọ́jà iná náà sì tàn dé ibùdó atọ́kọ̀se tó wà ní ẹ̀bá ibùdó ìdalẹ̀sí Olúsosùn náà.

Ní báyìí, àwọn ọ̀lọ́pàá ti gba àkóso agbègbè náà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: