Obafemi Awolowo: Nínú ilé tí wọ́n kó ńkan ídánimọ̀ Baba Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ sí

Obafemi Awolowo: Nínú ilé tí wọ́n kó ńkan ídánimọ̀ Baba Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ sí

Àgbà ọ̀jẹ̀ olósèlú tó tún jẹ́ gbajúgbajà ọmọ Yorùbá ni Obáfẹ́mi Awólọ̀wọ́ nígbà ayé rẹ̀.

Wo awọn nkan to wa nile oloogbe agba iran Yoruba naa, Oloye Obafemi Awolowo ni ilu rẹ ni Ikenne Remo nipinle Ogun ni Iwo oorun guusu Naijiria.

Nibẹ ni a ti ri awon nkan ti ọkọ Hannah Idowu Dideolu Wolowo lo kẹyin nigba aye rẹ bii kóòmù iyarun, atike mọju, ipara, ọkọ ayokẹlẹ to fi polongo idibo ọdun 1979 ati 1983\.

Tun wo ibi ti wọn sin olori iran Yoruba naa si ni Ikenne

Iru awọn iroyin ti ẹ le nifẹ si: