Ojúùtú ti wà fún àìsàn ibà
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ọ̀nà àbáyọ de láti gbẹ̀san lára Ẹ̀fọ̀n mujemuje tí yọjú

Abewo ikọ BBC sì Laabu àwọn àṣẹwádìí ọhun ní ìwọ̀-ọrùn Kenya fi hàn pé ẹniti o ba ti lo òògùn Ivermectin, ẹ̀jẹ̀ wọn yóò jẹ májelè fáwọn ẹfọn, èyí pẹ̀lú yóò jẹ iranwọ láti jẹ ki Ẹ̀fọ̀n máa tàn kalẹ.