Koko iroyin: Awuyewuye Buhari bu awọn ọdọ, Ìpade Commonwealth

Eyi ni awọn akojọpọ iroyin ti toni.

Iléeṣẹ́ ààrẹ: Buhari kò bú ọdọ, àwọn ọ̀bàyéjẹ́ ń pa irọ́

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán,

Iléeṣẹ́ ààrẹ ní ojúṣe ìjọba ni láti pèsè àyè tó tọ̀nà sílẹ̀ fún olúkúlùkù láti mú àlá rere wọn ṣẹ.

Lori ọrọ kan ti o n ja rayin-rayin ti wọn ni aarẹ Buhari sọ nilu London pe ọkundun ti ko fẹ iṣẹ ṣe lawọn ọdọ Naijiria, ileese aarẹ orilẹede Naijiria ti sọ pe, ọrọ ko ri bẹẹ; atipe awọn ọbayejẹ ẹda kan lo fẹ ti ibi ohùn mu aarẹ.

Iroyin sọ pe ilu Lọndon ni A awọn olori orilẹede to wa labẹ ajọ Commonwealth.

Nípínlẹ̀ Ògùn, Ọ̀gá ọlọpàá yìnbọn jẹ

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán,

Àwọn ìdílé olóògbé náà kò mọ ìdí tí olóògbé Agholor fi gbé ìgbésè náà

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán,

Ààrẹ Buhari ní awọn eeyan Naijiria gbọdọ di opo iwa ootọ mu ki wọn si gbe igbe aye to duro daadaa

Ọ̀gá ọlọpàá kan tó ti fẹ̀yìntì tí orúkọ rẹ ń jẹ́ David Agholor, ti gb'ẹ̀mí ara rẹ̀ ní Ìjokò ní ìpínlẹ̀ Ògùn.

Agbenusọ ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ náà, Abímbọ́lá Oyèyẹmí, sọ fún BBC wípé ọmọ olóògbé Agholor ló fi tó àwọn ọlọ́pàá létí wí pé bàbá òun ti yìn'bọn pa ara rẹ̀ lẹ́yìn tí ó jí tí ó sì wẹ̀ ni ọjọ́ Ọjọ́bọ ní ilé rẹ̀ tó wà lágbègbè Sheraton Estate tí ó wà ní Ìjokò. E ka ekunrere re ni bii

Awọn nkan miran ti ẹ ni lati mọ loni

Gbọ iroyin iṣẹju kan BBC

Fidio wa fun toni

Àgbà ọ̀jẹ̀ olósèlú tó tún jẹ́ gbajúgbajà ọmọ Yorùbá ni Obáfẹ́mi Awólọ̀wọ́ nígbà ayé rẹ̀.

Àkọlé fídíò,

Igbe àyé Ọbáfẹ́mi Awólọ̀wọ́ nigba aye rẹ̀