AfricanDrumFestival: Àwọn àwòrán tó làmìlaaka níbi ayẹyẹ

Awọn aworan to lamilaaka nibi ayẹyẹ ajọ̀dún ìlù nílú Abẹ́òkúta.

Gbagede ibudo ayẹyẹ ajọdun ilu nilu Abẹokuta
Àkọlé àwòrán Aarẹ Muhammadu Buhari ṣe ileri atilẹyin fun idagbasoke aṣa
Aworan olumo rock
Àkọlé àwòrán Ọna abawọle si ori oke olumọ
Ọmọde kan ati awọn akẹgbẹ n lu ilu Image copyright AfricanDrumFestival
Àkọlé àwòrán "Kani a mọ pataki idagbasoke aṣa si idagbasoke eto ọrọ aje wa, a o tẹpa mọ"
Ọmọde kan ati awọn akẹgbẹ n lu ilu Image copyright AfricanDrumFestival
Àkọlé àwòrán Ó lé ní ogún ìpínlẹ̀ tí yóò kópa níbi ayẹyẹ àjọ̀dùn ìlù nílẹ̀ Áfíríkà náà
Aworan ojogbọn Soyinka,Minista Lai Mohammed ati Gomina Ibikunle Amosun Image copyright AFRICAN DRUM FESTIVAL
Àkọlé àwòrán Ijọba ipinlẹ Ogun lo n ṣe agbatẹru ajọdun ilu ilẹ Afirika
Alaafin ti ilu Ọyọ, Ọba Lamidi Adeyemi III Image copyright AfricanDrumFestival
Àkọlé àwòrán Awọn ọbalaye kan sara si awọn agbaṣaga
Oṣere kan n fi ilu ṣere Image copyright AfricanDrumFestival
Àkọlé àwòrán Àgba awọn to wa nipo aṣẹ lẹka iṣejọba gbogbo niyanju lati rii wei pe wọn n ṣe koriya fun igbedide aṣa ilẹ Yoruba.
Awọn eekan oṣere Olu Jacobs, Kareem Adepọju ti ọpọ eeyan mọ Baba wande Image copyright AfricanDrumFestival
Àkọlé àwòrán Ọkan ojọkan awọn gbajugbaja olosere ni wọn yoo kopa nibi ajọdun naa
Aworan Baba Wande
Àkọlé àwòrán Agba osere Nollywood ko gbẹyin nibi ayẹyẹ naa
awon eniyan marun kan gbe ejo dani
Àkọlé àwòrán Awọn onidan naa se bi ọkunrin nibi ayẹyẹ ilu

Awọn aworan yii wa lati ọwọ: BBC ati AfricanDrumFestival

Ní àyíká BBC