Àjọ̀dún ìlù ilẹ̀ Afrika
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

'Ìlù jẹ́ ohun èlò fún ìgbésí ayé ọmọ Yorùbá'

Àwọn akópa níbi ọdún ìlù ilẹ̀ Afrika tó wáyé nílu Abẹ́òkuta fí ìdùnú hàn pè ètò yìí wà lára ohun tí yòó gbe àsà ilẹ̀ Yorùbá ga.

Tó fi mọ́ àwọn olósèlú àtàwọn eléré tíátà, wọ́n ní láti ìbẹ̀rẹ̀ ni ìlù ti wà wọ́n sì gbàgbọ́ pé káàkiri àgbáyé ni wọ́n ríi pé àsà tó kúná í kò sì sseé fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn ni àsà Yoruba.