Abúlé Òkè Àró: A nílò ìrànwọ́ láti ta ẹlẹ́dẹ̀ nílẹ̀ òkèèrè

Abúlé Òkè Àró: A nílò ìrànwọ́ láti ta ẹlẹ́dẹ̀ nílẹ̀ òkèèrè

Ọ̀sìn ẹlẹ́dẹ̀ ti di ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ àwọn obìnrin báyìí, tí wọ́n sì ń tọ́jú rẹ̀ bíi ọmọ.

Abúlé Òkè Àró ní ìpínlẹ̀ Ògùn sì ni àwọn obìnrin ti ní ànfààní láti gba ibùdó ọ̀sìn ẹlẹ́dẹ̀ kan fún ara wọn.

Àwọn obìnrin tó bá BBC Yoruba sọ̀rọ̀ ní, àwọn ń fẹ́ ìrànwọ́ ìjọ̀ba ní ìdí owónàá, àyẹ̀wò ìlera fáwọn ẹlẹ́dẹ̀ àti kíkó wọn lọ tà nílẹ̀ òkèèrè.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: