‘Òkè ni àsẹ ti wa láti mú Dino’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Agbẹnusọ Mélayé: Dino ti lọ yọjú sọ́dọ̀ ọlọ́paa SARS

Agbẹnusọ fun Sẹ́nẹ́tọ̀ DIno Mélayé, Gideon Ayọ̀délé sọ fún BBC Yorùbá pe àsẹ kò wá láti iléẹjọ́ rara pé kí wọn gbe Dino, sùgbọ́n o ti wa ara rẹ̀ lọ sọ́dọ̀ ọlọ́paa SARS ní àárọ̀ ọjọ́ ìsẹ́gun.

Ó ní àwọn ọlọ́paa tó mú Dino ní pápákọ̀ òfurufú sọ pé òkè ni àsẹ ti wa láti mú Sẹ́nẹ́tọ̀ náà.

Ó fikún pé Ẹ̀ẹ̀mejì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni wọn gbèrò láti pa Dino Mélayé nítorí òtítọ̀ tó máa ń sọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: