Ń jẹ́ o mọ orísi ọ̀gẹ̀dẹ̀ tó wà?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Orísi ọ̀gẹ̀dẹ̀: Sàró lo mọ̀ ni àbí Pàǹbo?

Ọ̀gẹ̀dẹ̀ jẹ́ kòsemáánìí ní inú ilé, tí orísirísi wọn sì ní ohun tó ń se fún ara.

A gbọ́ pé ọ̀gẹ̀dẹ̀ dára fún ìpanu, ìwòsàn àìsàn àtọ̀gbẹ àti fún ohun mínu.

Onísòwò ọ̀gẹ̀dẹ̀ kan, aya Mákànjúọ́lá tiẹ̀ salàyé àwọn orísi ọ̀gẹ̀dẹ̀ tó wà àti ìwúlò wọn.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: