Sẹ́nẹ́tọ̀ pe ọ̀gá ọlọ́pàá lórí ọ̀rọ̀ Dino
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Àwọn aṣòfin so ìjókòó rọ̀ nítorí Dino Melaye

Alákóso ẹgbẹ́ tó n rí sí bí ìjọba àwarawa yóo ṣe fẹsẹ̀ múlẹ̀, ọ̀gbẹ́ni Adéọlá Ṣóẹ̀tán, sọ pé, Dino ń se àpèjúwe bí àwọn olóṣèlú orílẹ̀-èdè Nàíjìrà ti rí ní àsìkò yìí.

Adéọlá Ṣóẹ̀tán pàrọwà fáwọn eǹìyàn Nàìjííà láti má sọ ìrètí nù lórí ètò òṣèlú Nàìjííà