Ilé-ẹjọ́ ìlú Èkó fi Nwaoboshi sátìmọ́le fún ìkówójẹ

Àwòràn Nwaoboshi Image copyright Nwaoboshi /twitter
Àkọlé àwòrán Ilé ẹjọ́ fi Peter Nwaoboshi sátìmọ́lé di òpin ọ̀sẹ̀

Ilé-ẹjọ́ ìjọba àpapọ̀ tí Ìlú Èkó tí sọ Sẹ́nétọ̀ Peter Nwaoboshi tíì ṣe ọmọ ẹgbẹ́ People's Democratic Party tó ń soju fún ẹkùn Delta North sewon.

Muhammed Idris dájọ pé kí Nwaoboshi wà látìmọ́lé di ọjọ́ Jimo tí ilé ẹjọ́ yóò fi ṣe àgbéyèwò gbígba oniduro rè.

Àjọ EFCC ló gbé Sẹ́nétọ̀ náà lọ sile ẹjọ́ lórí ẹ̀sùn ikowo ìlú pamọ́.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: