Sambisa: Yóò di ibi ìgbàfẹ́ láìpẹ́ ọjọ́

Àwòrán àwọn ọmọogun nínú ọkọ̀ Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ìbáṣepọ̀ àjọ ọmọogun pẹ̀lu ìjọba ìpínlẹ̀ Borno yóò ran àtúnṣe sambisa lọ́wọ́

Olórí àwọn ọmọogun orile-ede Naijiria Tukur Buratai sọ pé ibùdó àwọn Boko Haram tẹ́lẹ̀ rí nínú igbó sambisa kò ní pẹ di ibi ìgbàfẹ́.

Tukur sọ̀rọ̀ yìí lásìkò tí àjọ tó ń rí sì ìrìn-àjò ìgbàfẹ́ sabewo sii.

Ó ní Àjọ tó ń mojuto irinajo ìgbàfẹ́, ìjọba Ìpínlẹ̀ Borno àti àjọ ọmọogun tí ń jíròrò lórí kókó náà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ó ní sísọ ìbè di ibi ìgbàfẹ́ yóò fi ìgbàgbé sí àwọn tí tí ṣẹlẹ̀ yóò sì tún mú ìlò igbó Sambisa kojú òṣùwọ̀n