Kókó ìròyìn: Òrọ̀ lórí lílo ewé áti egbò fún àìsàn ibà

Èyí ni àwọn àkójọpọ̀ ìròyìn ti tòní.

Àìsàn ibà; Àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ nípa lílo ewé áti egbò

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionÀìsàn ibà; Àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ nípa lílo ewé áti egbò

Ọjọ́ Karùndínlọ́gbọ̀n, Oṣù Kẹrin ọdọọdún ni Àjọ Àgbáyé yà sọ́tọ̀ láti kọjù ìpèníjà àisan ibà tó wọ́pọ̀ ní ilẹ̀ Afirika, èyí tó ti ṣekúpa ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn.

Ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ èèyàn bẹnu ẹ̀tẹ́ lu ìbẹ̀wò àwọn aṣòfin sí Dino láìṣe iṣẹ́ ìlú

Image copyright Aminu Omoye
Àkọlé àwòrán Ọnà tí Dino fi farapa nínú ìṣẹ̀lẹ̀ náà kò tíì dájú

Ọ̀rọ̀ ti bẹ́yìn yọ báyìí bí àwọn ọmọ Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà l'Abuja ti so ìjókòó rọ̀ nítorí Dino Melaye l'ọ́jọ́rú láti lọ ṣàbẹ́wò sí Dino Melaye

Àwọn Sẹ́nẹ́tọ̀ náà korò ojú sí bí àwọn ọlọ́ọ̀pá ṣe mú Dino Melaye, tí gbogbo wọn sì lọ wòó ní ilé ìwósàn.

Sẹ́nétọ̀ Nàìjíríà tó ń lo ayédérú ìwe ẹ̀rí

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionNUC: 'Ayédèrú n'ìwé ẹ̀rí sẹ́nétọ̀ Foster'

Sẹ́nétọ̀ Ogola tó ti ń sàfihàn àseyọrí ìwé ẹ̀rí tó sì ti ń lò ó fún pàtàkì òsèlú rẹ̀.

Sùgbọ́n ní báyìí, ìwádìí fi hàn pé àwọn ìwé ẹ̀rí oyè Phd tó gbà nínú ìmọ̀ adarí krìstẹ́nì èyí tó gbà láti fásitì tí àjọ NUC kò fọwọ́ sí jẹ́ ayédèrú.

Àwọn ǹkan míràn tí ẹ ní láti mọ̀ lónìí.

Gbọ iroyin iṣẹju kan BBC

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionÌsẹ̀lẹ̀ jákèjádò orílẹ̀èdè àgbáyé láàárín ìṣẹ́jú kan

Fidio wa fun toni

'Kò sí ẹni tí èmi kò lè firun èèyàn yàwòrán rẹ̀'

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionIrun gígẹ̀ kọjá orí fífá lásán