Nàìjíríà: kọ́ ọgbà fún ẹran ọ̀sìn rẹ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

NEC fi òfin de dída ẹran ọ̀sìn kiri nìpínlẹ̀ márùn uń

Ogbẹ́ni Tever Akase, tó jẹ́ agbẹnusọ ìpínlẹ̀ Benue, ba BBC Yoruba sọ̀rọ̀ pé ohun tó kù ni kí ìjọba àpapọ̀ pàṣẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ elétò ààbò pé kí wọ́n fi òfin náà múlẹ̀ bí ó ti yẹ káàkiri