Àwọn òsìsẹ́ Ọ̀yọ́ ń fẹ́ ètò ìdẹ̀rùn tó péye
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ẹgbẹ́ òsìsẹ́ Ọ̀yọ́: Àsìkò tó fún ìgbéga ìgbé ayé òsìsẹ́

Níbi ayẹyẹ àyájọ́ òsìsẹ́ fún tọdún 2018 lawọn òsìsẹ́ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yó ti ń figbe bọnu fún ìpèsè ètò ìdẹ̀rùn tó péye lọ́dọ̀ ìjọba.

Àwọn ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ òsìsẹ́ náà ní ipò tí ọ̀pọ̀ òsìsẹ́ wà báyìí kò dára rara, tí wọn sì ń ké sí ìjọba láti tètè dìde fún ìrànwọ́ àwọn òsìsẹ́.