'Ọpẹ́lọpẹ́ Ìbàdàn lára Yorùbá'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Olóyè Àlàbí dárúkọ àwọ́n adárí Yorùbá tó mòye

Àgbààkin Olúbàdàn ti ilẹ̀ Ìbàdàn, Olóyè Lékan Àlàbí sọ́ pé Ìlú Ìbàdàn ló gba ìran Yorùbá sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn akónilẹ́rú JIHAD ti ìhà àríwá orílẹ̀èdè Nàìjíríà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: