Gbajúgbajà òsèré tó tún mọ́ ọbẹ̀ sè
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Òsèré Nollywood; Dayọ̀ Amúsà jẹ́wọ́ ara rẹ̀ lórí ètò Àjẹpọ́nulá

Gbajúgbajà òsèré tíátà Yoruba, Dayọ̀ Amúsà kò kàn jẹ́ obìnrin òsèré lásán, ó tún jẹ́ obìnrin nínú ilé.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: