Naijiria kò gbàgbé ààrẹ tó d'olóògbé l'ọ́dún mẹ́jọ sẹ́yìn

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Yar'Adua di oloogbe ni oṣu karun ọdun 2010

O pe ọdun mẹjọ ni oni ti aarẹ ana Umaru Musa Yar'Adua di oloogbe nigba ti o wa l'ori aleefa. Sugbọn awọn ọmọ Naijiria ko gbagbe o.

Wọn ṣe iranti rẹ ni ori Twitter.

Yar'Adua di oloogbe lati ọwọ aisan ọkan ni ọjọ karun oṣu karun ọdun 2010. Igbakeji rẹ Goodluck Jonathan si gori aleefa lẹyin rẹ.