Iṣẹ́ orí rán mi ní mo lọ kọ́, ti mò ń ṣe fi jẹun
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Olumide Ọrẹsẹgun: Ẹni mọ iyì wúrà ni mo ń ta awòrán fún

Olumide Orẹṣẹgun, gbajúgbajà ayàwòrán sọ̀rọ̀ lórí oríṣii àwòrán tó wa àti ìmísí lórí àwòrán yíyà.

Ọrẹsẹgun ni ni ọpọlọ, suuru àti agbára ni oun ń lò lati f

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: