Ọdọ́ Tunisia yóò yan ẹni tó wù wọn sípò nídìbò abẹ́lé

Asia orile ede Tunisia Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Àwọn ènìyàn Tunisia ń fẹ́ òmìnìra lẹ́yìn ìdìbò òní

Ẹẹmẹrin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni wọn ti sún ètò ìdìbò abẹ́lẹ́ Tunisia síwájú

Ìdìbò 2011 ni wọn ti dìbò lórí adari Zine El-Abidine Ben Alil.

Oṣù kẹsan an ọdun to kọja ni àwọn ile igbimọ aṣofin foríji àwọn tijọba tó kógbá wọlé fẹ̀sùn jẹgúdújẹrá kàn.

Odún 2010 ni wọn dìbo ijọba ìbìlẹ̀ bayii kẹ́yìn.

Awọn ọ̀dọ̀ Tunisia ń wòye fún ọjọ́ iwájú rere lẹyìn ìdìbò òní.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: