Olúbàdàn: Ìgbésẹ̀ Ajimọbi tako ìsèjọba ìsẹ̀ǹbáyé

Gómìnà Abiọla Ajimọbi àtàwọn ẹ̀sọ́ rẹ̀

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán,

Olúbàdàn àti gómìnà Ajimọbi wojù ara wọn lórí oyè jijẹ nilú Ìbàdàn

Osi Olubadan ti ilẹ Ibadan, Rashidi Ladoja lo pe ọkan lara awọn ọba alade tuntun naa lẹjọ.

Ladọja jare n'ilẹ ẹjọ lori bi o ti lodi si awọn ijoye pẹlu awọn baalẹ ti ijọba sọ di ọba.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Osi Olubadan ti ilẹ Ibadan, Rashidi Ladoja lo pe ọkan lara awọn ọba alade tuntun naa lẹjọ.

Ladọja jare n'ilẹ ẹjọ lori bi o ti lodi si awọn ijoye pẹlu awọn baalẹ ti ijọba sọ di ọba.

Ijọba Ọ̀yọ́ ní igbesẹ naa tọna

Ṣugbọn Gomina ipinlẹ Ọyọ Abiola Ajimobi lọ sile ẹjọ ko tẹmilọrun lori ọrọ naa.

Ijọba só di mimọ pe igbesẹ naa tọna lẹyin ipade pẹlu awọn lọbalọba ni ipinlẹ Ọyọ.

Ṣugbọn agbẹjọro fun Olubadan, Adeniyi Adewọle,sọ pe gomina ko lágbara lati s'epade pẹlu awọn ọba alaye.