Ó yẹ kí àwọn asòfin yọ Buhari - Shiite
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Shiite: Tinúbú, bá Buhari sọ̀rọ̀ kó tú ZakZaky sílẹ̀ kó tó pẹ́ jù

Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ẹlẹ́sìn Shiite ti fọnmú, tí wọn sì sèwọ́de lọ sọ́dọ̀ asaájú ẹgbẹ́ òsèlú APC, Bọ́lá Ahmed Tinubu ní ìlú Èkó.

Àwọn ọmọ ẹgbẹ Shiite náà ń fẹ́ kí Tinubu bá Buhari sọ̀rọ̀, kó tètè tú Zakzaky sílẹ̀ ní àhámọ́, kó tó pẹ́ jù.

Bákan náà, ni wọ́n ń késí àwọn asòfin Nàíjíríà láti tètè yọ ààrẹ Muhammadu Buhari nítorí kò tẹ̀lé òfin orílẹ̀èdè yìí.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: