PDP sọ̀rọ̀ lórí ìkọ̀wéfipòsilẹ́ Ọlagunsoye Oyinlola
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Oyinlọla kọ̀wé fipò rẹ̀ sílẹ̀ ni NIMC

Emi kò jẹ́ dalẹ̀ ọga mi lẹ́nu iṣẹ́, ṣùgbọn tọ ipa ti ọkàn mi fẹ́ lásìkò yii ninu òṣèlu.