Tẹlifísàn Sudan: Ó dàbí pé wọn fi ọ̀bẹ gún asojú Nàíjíríà pa ni

Àtọ́ka Sudan
Àkọlé àwòrán Wọn ní o ṣeeṣe kó jẹ́ pé wọ́n ṣeku pa á ni

Wọ́n ti rí òkú aṣojú orílẹ̀èdè Nàìjíríà kan ní Sudan. Ìwádìí sì ti bẹ̀rẹ̀ lọ́gán ki ọ̀rọ̀ nàá tó lu síta.

Nínú ilé kan tó wà ní Khartoun, tíi ṣe olú ìlú fún Sudan, ni wọ́n ti rí òkú nàá. Kò tí i sí ẹnikẹ́ni tó mọ́ òhun tó ṣekú pa a.

Àmọ́, iléeṣẹ́ amóhùn-máwòrán Al-Arabiya, ti ṣàpéjúwe ikú tó paa gẹ́gẹ́ bí ''ìṣekúpani'', táwọn kan sì n sọ pé, wọ́n fi ọ̀bẹ gun un pa ni.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionShiite: Tinúbú, bá Buhari sọ̀rọ̀ kó tú ZakZaky sílẹ̀ kó tó pẹ́ jù

Aó maa fún yín ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn nàá, bí ó bá ṣe n tẹ̀wá lọ́wọ́.