Tinubu: kò sí àṣàdànù nínú gbogbo olùdíje APC Ekiti

Bola Tinubu Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Gbogbo olùdíje APC Ekiti ló tó gbangba sùn lọ́yẹ́

Bola Tinubu ni òun kò ni ààyò kankan nínú àwọn olùdíje APC Ekiti

Èèkàn nínú ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), Bola Ahmed Tinubu, ti ni kò si ẹni ti kò tó o ṣe gomina nínu gbogbo àwọn olùdíje APC Ekiti loni.

O ni àtilẹyin kan naa ni òun ń ṣe fún gbogbo wọn papọ.

Ati pé oun ko ni ayanfẹ ọ̀tọ̀ ninu gbogbo wọn.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: