Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ àti ìyàwó rẹ̀ kò gbẹ́yìn nínú ìdìbò tó ń lọ

Àwòrán Gomina ọyọ àti ìyàwó rẹ
Àkọlé àwòrán Gómìnà Abiola Ajimọbi àti ìyàwó rẹ̀ níbi ìdìbò yan alága kánsù

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Abiọla Ajimọbi àti ìyàwó rẹ̀ ló kọ́wọ̀ọ́rìn lọ sí ibi àpótí ìdìbò ti wọn.

Wọ́ọ̀dù kẹsàn-án nínú ọgbà ilé ìwé Girama ní Olúyọ̀lé, ìlú Ìbadan ní àpótí ìdìbò wọn wà gẹ́gẹ́ bí akọ̀ròyìn wa tó ń mójú tó ètò ìdìbò náà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ sọ

wọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: