RAMADAN: Onímọ̀ ẹ̀sin sọ nípa isẹ́ láádá àti làádà nínú oṣù mímọ́

Oṣù Ramadan jẹ pàtàkì oṣù fún àwọn mùsùlùmí jakejado àgbáyé.

Nínú oṣù náà òpó iṣẹ ẹsìn àti itore a má wáyé.

Ṣugbọn ẹni ti kò bá mọ ọnà tí wọn ṣe n ṣe, yóò kàn f'ebi pa inú lásán ni.

A ba onimọ ẹsìn,ọjogbọn Nasirudeen Bello sọrọ lórí àwọn nnkan to ye ki ẹ ṣé lati le ni láádá ati làádà to wa ninu oṣù náà.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: