Ọkùnrin tó ń dín àkàra tà bíi obìnrin
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Alákàrà tó ta lẹ́nu: Tí o bá tijú, o kò le è lówó

Ọlátúnjí James, tí wọn tún ń pè ní Alákàrà tó ta lẹ́nu sọ fún BBC Yorùbá pe ilé ẹ̀kọ́ gbogbo-nse Poly tìpínlẹ̀ Ọ̀sun ni òun ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa òkòwò, eyiun Business Administration.

James ni o sú òun láti da ìjọba láàmú fún isẹ́ osù ló mú kí òun máa dín àkàrà tà.

Ò wá gba àwọn ọ̀dọ́ ní ìmọ̀ràn láti ronú bí wọn yóò se gba àwọn èèyàn sísẹ́, dípò kí wọn máa wá isẹ́ kiri lọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: