Fídíò Aisha rèé, tó ń báwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ seré
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ọmọge Campus: Èmi kò dàgbà jù yín lọ, ẹgbẹ́ ni wá

Nínú fídíò yìí ni Olóògbé Aisha Abimbọla ti ń dá àpárá pẹ̀lú àwọn akẹẹgbẹ́ rẹ̀ lóbìnrin nínú tíátà, pé òun àti wọn ni ẹgbẹ́.

Lára àwọn akẹẹgbẹ́ rẹ̀ tí wọn jọ wà nínú ọkọ́ ayọ́kẹ́lẹ́, tí wọ́n dìjọ ń se àwàdà ni Aisha Lawal, Sheyi Asekun àti ọmọge miran.

Fidio yìí se àfihàn pé onírẹ̀lẹ̀ ni Aisha Abimbọla, tó sì ń kó àwọn òsèré tó ń bọ̀ lẹ́yìn rẹ̀ mọ́ra.

Aisha Lawal lo fi fidio naa sita loju opo Istagram rẹ lati se iranti Aisha Abimbọla.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: