Koko iroyin: Iyiọla Omisore darapọ̀ mọ́ SDP, Ọwọ́ tẹ agbésùnmọ̀mì ní yobe

Eyi ni awọn akojọpọ iroyin ti toni.

OmiṣoreỌlọ́run mọ̀ sí bí òun ṣe fi PDP sílẹ̀.

Oríṣun àwòrán, Iyiola Omisore/Facebook

Àkọlé àwòrán,

Omiṣore ti kọ́kọ́ dupò gómìnà lábẹ́ àsìá PDP lọ́dún 2014

Igbákejì gómìnà ìpílẹ̀ Ọ̀ṣun nígbà kan rí, Sẹnatọ Iyiọla Omisore ti fi ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party, PDP sílẹ̀.

Omisore fi PDP sílẹ̀ lọ sínú ẹgbẹ́ òṣèlú Soc, níbi tó ti ní ìrètí láti díje dupò gómìnà nínú ètò ìdìbò gómìnà tí yòó wáyé lọ́jọ́ kejìlélógún, oṣù Kẹsàn án.

Ilé-isẹ́ olóogun Nigeria: Ará ìlú dá ìkọlù dúró ní Yobe

Oríṣun àwòrán, Twitter/Nigerian Army

Àkọlé àwòrán,

Lilo awọn agbesunmọmi to jẹ ọmọde tabi obinrin jẹ ọna kan gboogi ti ikọ Boko Haram ma n lo lati se ikọlu.

Ile-isẹ ologun lorilẹede Naijiria sọ pe awọn ọmọ Naijiria rere ti dawọ ikọlu obinrin agbesunmọmi to fẹ se si mọsalasi kan ni abule Gashua, ni ijọba ibilẹ Gubja ni ipinlẹ Yobe.

Adari ikọ ipolongo fun ikọ ọmọogun ‘Operation Lafia Dole’,Onyema Nwachukwu ni "ti ko ba si ti awọn ara ilu ati awọn ọlọdẹ ibilẹ to ba igbimọ awọn agbesunmọmi naa jẹ, ibugbamu na o ba ba nkan jẹ. E ka ekunrere re ni bii

Awọn nkan miran ti ẹ ni lati mọ loni

Gbọ iroyin iṣẹju kan BBC

Fidio wa fun toni

James Ó ta lẹ́nu: Ìwọ tó o bá ń tijú, o ò le dé 'bi gíga

Àkọlé fídíò,

Akàwégboyè alákàrà