Wọ́n ti yọ igbákejì olórí ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ Òǹdò

Ami idanimọ ipinlẹ Ondo

Oríṣun àwòrán, Ondo state government

Àkọlé àwòrán,

Àwọn aṣòfin ìpínlẹ̀ náà tún dìbò yan ẹlòmíràn sí ipò rẹ̀

Wọn ti yọ igbakeji olori ile aṣofin ipinlẹ Ondo, Ogundeji Iroju kuro nipo.

Nibi ijoko ile naa ni ọjọ iṣẹgun ni awọn ọmọ ileegbimọ aṣofin ipinlẹ naa ti dibo yọ Ogundeji Iroju.

Bakannaa ni wọn si ti tun fi Aṣofin Bimbo Fadoju rọpo rẹ.

Ẹkunrẹrẹ iroyin n bọ laipẹ.