Koko iroyin: awon elere tiata sedaro aisha abimbola, ‘Fani-Kayode n fa Cocaine’

Eyi ni awọn akojọpọ iroyin ti toni.

Àwọn òsèré: Ìgbé ayé Ọmọge Campus jẹ́ ẹ̀kọ́ fún wa

+

Àkọlé fídíò,

Àwọn òsèré: Ìgbé ayé Ọmọge Campus jẹ́ ẹ̀kọ́ fún wa

Ìkẹ̀jà pa lọ́lọ́ lálẹ́ ọjọ́rú nígbàtí àwọn òsèré tíátà tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ pẹ̀lú àbẹ́là lọ́wọ́ wọn èyí tí wọn fi ń se ẹ̀yẹ ìkẹyìn fún Aisha Abimbọla.

Àwọn gbajúmọ̀ òsèré bíi Saheed Balogun, Sọla Kosọkọ, Sunkanmi Ọmọbọlanle ati ajàfẹ́tọ̀ọ́ ẹni, Okei Odumakin ni wọ́n se ìdárò olóògbé náà.

Wọ́n fi kún-un pé Obìnrin dúndùn abi ìwà dúndùn ni Aisha.

Festus Keyamo ni cocaine tí Femi Fani-Kayode ń fà ní o da orí rẹ rú

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán,

Bi ó tilẹ̀ jé pé Ààrẹ Muhammadu Buhari kò dárúkọ Ààrẹ kankan nínú ọrọ rẹ̀

Àwọn olólùfẹ́ ààrẹ méjèèjì sọ̀rọ̀ òdì sí ara wọn nítorí ẹ̀sùn bílìọ̀nù mẹ́rìndínlógún dọ́là tí Ààrẹ Muhammadu Buhari fí kàn ààrẹ àná, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ

Esun naa kò ṣẹyin owó bilìọ̀nù dọ́là mẹrindinlogun to yẹ fún iṣẹ́ mọ̀namọ́na lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí kò ní ipa lo tí dì ohun ti à ń gbà bí ẹní gba igbá ọtí láàárín àwọn èèkàn orílẹ̀-èdè yìí. E ka ekunrere re ni bii

Awọn nkan miran ti ẹ ni lati mọ loni

Gbọ iroyin iṣẹju kan BBC

Fidio wa fun toni

Ọmọge Campus jẹ́ ẹni tó kó ẹbí mọ́ra

Àkọlé fídíò,

Ọmọge Campus jẹ́ ẹni tó kó ẹbí mọ́ra