Gani Adams: 'Ìdàgbàsokè nínú ìmọ̀ ló jẹmí lógún'

Aworan Aare ona kakanfo ninu aṣọ ikẹkọgboye Image copyright Aare ona/Instagram
Àkọlé àwòrán Ọ̀pọ̀ àwọn ololúfẹ́ ààrẹ lo tí ń kíi kú oríre

Ààrẹ ọ̀nà kakanfò ilẹ̀ Yorùbá, Gani Abiodun Adams, gbá ìwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ ètò òṣelú, (political Science) nile ìwé gíga fáfitì ti ipinlẹ Eko.

Ààrẹ sọ èyí di mímọ̀ lóri ojú òpó ìkànsíraẹni Instagram rẹ.

Ó ní òún ṣe èyí fún ìdàgbàsókè ara òun nítorí pe òún fẹ́ran ìwé kíkà púpọ.

Bákan náà ló gba ọdọ níyànjú láti múrawọn dàgbàsókè nínú ẹ̀kọ́ ohun gbogbo ti wọn ba yàn láàyò.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ọ̀pọ̀ àwọn ololúfẹ́ rẹ̀ lo sì tí ń kíi kú oríre

Kò si ohun to ni ibẹrẹ ti kii ni òpin

Oloye Gani Adams ni aarẹ ọna kakanfo tuntun fun gbogbo ilẹ Yoruba.

Related Topics