Iparí UCL: Pápá ìṣiré Kiev gbàlejò Madrid àti Liverpool

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ẹgbẹ agbabọọlu Liverpool ni ẹgbẹ agbabọọlu akọkọ ni ilẹ Gẹẹsi akọkọ ti yoo de ipele aṣekagba

Wo bi gbagede papa iṣire Kiev, ti ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba idije Champions league yoo ti waye lọjọ Abamẹta.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Real madrid àti Liverpool yóò gbéná kojú ara wọn ní Pápá ìṣiré Kiev láti mọ ọba bọ́ọ̀lú àfẹsẹ̀gbá láàárín àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lú ní ilẹ̀ Yúróòpú
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Real madrid àti Liverpool yóò mọ ọba bọ́ọ̀lú àfẹsẹ̀gbá láàárín àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lú ní ilẹ̀ Yúróòpú lọjọ abamẹta
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Real Madrid ati Liverpool ti kọkọ pade ni ipele aṣekagba ni ọdun 1981
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Real Madrid vs Liverpool: Pápá ìṣiré Kiev ree
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Igba marundinlogun ni Real Madrid ti wọ ipele aṣekagba idije yii
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Igba meje ni Liverpool ti wọ ipele aṣekagba idije naa
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Real Madrid lo tii gba ife ẹyẹ Champions league ju
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Eyi ni igba kẹta laarin ọdun mẹta ti Real madrid yoo maa wọ aṣekagba idije Champions league