Jiganbabaoja: Àwa Yorùbá ò fi ọ̀rọ̀ ọjọ́ orí ṣeré

Aworan Abimbola Kazeem
Àkọlé àwòrán,

Abimbola Kazeem mẹnu ba ọr moju ẹ lọ o ju mi lọ ti ọpọ ni Naijiria ko fi sere rara

Bí eré ló bẹrẹ ṣùgbọ́n báyìí o tí gbà ilẹ̀

Kí o to bẹrẹ sí ní ká ìròyìn yi, jẹ kín kọkọ béèrè lọwọ ẹ pé ''ShoMoAgeMiNi?''

O mó age mí àbí?

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ajẹwipe o kò tí já sí àṣà tuntun tó gbà ìgboro ni yen.

Abímbólá Kazeem òṣeré tíátà Yorùbá lo dá àṣà náà lè.

Àṣà naa n da ìgboro rú

Nigba ti o n ba BBC Yoruba sọrọ, o ni ko ye oun bi àṣà #ShoMoAgeMiNi ti ṣé gbálè káàkiri.

''Mi o lérò wí pé àwọn èèyàn má tẹwọ gba àṣà náà bí wón ti ṣé gba báyìí. Mo kan ni kín da lasa ní láì ro wí pé yóò dá ìgboro rú to báyìí''

Ko fe sí ẹni tí kò má dá àṣà #ShoMoAgeMiNi pàápàá jù lọ láàrin àwọn òṣeré eré tíátà Yorùbá ati awọn olorin takasufe

Iha wò ní Yorùbá kọ sí ọjọ orí?

Ni ilẹ kaaro ojiire, ipò ọwọ ní ẹni tí o ba dàgbà má n wá.

Fún ìdí èyí òpó a má fẹ fìdí ọrọ múlẹ pé àwọn kìí ṣé ẹgbẹ́ ẹní tí kò tó wọn.

Jiganbabaoja salaye pe "Yoruba fẹràn ipo.Bi wọn bá bi ọmọ méjì nínú agbolé kannáà wọn a má sọ ara wọn nípasẹ ọjọ orí wọn láti má ṣe jẹ kí ẹnìkejì rí wọn fin.''

Abímbólá Kazeem dúpẹ lọdọ àwọn ololufẹ rẹ bí wọn ṣe tẹwọgbà àṣà 'ShoMoAgeMiNi?''

''Mo n gbìyànjú àti gbé fídíò orin jáde.Ẹ tẹti leko''