'Visionscape ń fìya owó oṣù jẹ wá'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Awọn agbálẹ̀ ní Ékó fẹ̀hónú hán ní ọ́fììsì Visionscape

Image copyright VISIONSCAPE
Àkọlé àwòrán Àwọn òṣiṣẹ́ Visionscape kò sọ̀rọ̀ lórí ẹ̀hónú náà

Yatọ̀ sí awuyewuye tí ó gbalẹ̀ kan lórí kíkó ìdọ̀tí ní ilú Eko tí ọ̀pọlọpọ̀ àwọn ará iìlú ń bẹnu àtẹ́ lu ilé iṣẹ́ Visionscape tí ó ń ṣe àkóso ọ̀rọ̀ ìdọ̀tí ní ìpínlẹ̀ náà, àwọn tí ó ń ṣiṣẹ́ lábẹ́ ile iṣẹ́ náà ti ké gbàjarè o.

Nígbà tí BBC gbìyànjú láti bá àwọn òṣiṣẹ́ Visionscape sọ̀rọ̀, wọn kọ̀, wọ́n ní àwọn kò ní nkankan láti sọ lórí ọ̀rọ̀ náà.

Related Topics